
Telegram Link Join Now Join Now
(Verse 1)
Awon adan fo loke, won fanka s’oju orun, won ma mobi won lo, Eledua lon s’ke wonKo keyin sile ore oh, oun o’n wa o wa ni iwaju re
(Chorus)
Adedotun oun dawon la mi, ero gbogbo e bami gberin, Adedotun oh
(Verse 2)
Awon Adan fo loke, nigba igba won kun oju orun, won ma mo oun wonje, Eledua lo n so won lo n bo won
Ko pawon sile ore oh, oun wa lo sokoto, o wa la po sokoto
(Chorus)
Adedotun oun dawon la mi, ero gbogbo e bami gberin, Adedotun oh
(Outro)
Ko pawon sile ore oh, oun o’n wa o wa ni iwaju re oh